• LYRICS • view
Kape laye Ka lo Ile aye titi
Ko ni Kaye gbo ooooooo
Aye lole lo niyan keee gbo
Igba ta gbe laye Ohun a gbe Ile aye she gbogbo
Keledua je kaa le pitan rere
{Edmuare Edumare, ope mi po lodo re }x
omi aye to ru siwa seyin o
{Iwo loo o je ko gbemi lo }2x
awon kan gbaye won pitan ise titi,
won pitan isoro kolopin rara,
oro won o papa jasayo o mase, ojo jo aye ni won foju sogbere eku,
titi iku fi pa won, won ko lelu dupe.
{Edmuare Edumare, ope mi po lodo re }x
omi aye to ru siwa seyin o
{Iwo loo o je ko gbemi lo }2x
Awọn kan gb’ayé wọn jadun ayé Títí won gbàgbé asèdá t’oda ayé
Ọrọ’ ayé rú bo wọn lójú jọjọ alumoni Wọn l’ayé wọn f’ogo rẹ fún satani nii
Igbagbe ṣewọn pé òun gbogbo tọwọ asèdá wa o’mase o’mase
{Edmuare Edumare, ope mi po lodo re }x
omi aye to ru siwa seyin o
{Iwo loo o je ko gbemi lo }2x
Uploaded on Dec 20, 2021
Tope Alabi - Kape Laye - music Video
Share this Video
- 113
Views
Comment on "Tope Alabi - Kape Laye video "
This Week's Top Song
Boney M Christmas Album |
Boney M
Downlod Song
Play Song
Trending
RECENT SEARCHES (0)
VIEW ALLFeatured Song
Twalibaddewa |
Grace Nakimera
Downlod Song
Play Song