ADEOLA MARTINS LYRICS

"OLORUN ARA" From GMP PROMOTIONS

OLORUN ARA(GOD OF WONDERS) LYRICS:
Chrs
Ara re po o, Olorun Ara,
Ara re po o , Olorun Ara,
Ara lo fi fomo pa mo sinu obinrin , Ara re po o,
Ara lo fi fomi pa mo sinu agbon ara re po o

Verse 1. Olorun to daye atorun , Ara re po o,
Ohun re to fa go kedari ya, Ara lo fi see
You made the world your foot stool ,my Lord you are so great,
You are the unquestionable God
Ara re po o o

Verse 2.
Ta lole tuse re wo o ,Olorun Agbaye,
Ojo to nro le gbogbo eda Lori nibo lotiwa,
Sanmo ti ataa lewa Lori nko , ki lo gbe duro,
Everything we see about you is Great ,Ara re po oooo

Call:Ara ni o ,Olorun Ara o
Res: Ara ni ooo
Call:Gbogbo ise re ta nri laaye Ara no
Res Ara ni oo
Call: Sanmo ti ata lewa lori ara ni
Res: Ara ni o
Call: Baye se Tobi to Apoti itise lofi we
Res: Ara ni o
Call: Baba Iwo lo tobi, Oga, Ofe, Opor
Call:Jesu mi to nsise ara
Res: Ara ni o
Call:Ola fi we ,Ola fijo
Res: Ara ni o
Call:Alagbara,Alagbara ni
Res: Ara ni o
Call:Everything I see about you is great
Res: Ara ni o
Call: Ko seni ti mo le fi o we
Res: Ara ni o

Vamp: Ara ni o,Olorun Ara, Kosun ti mo le fi o owe, Ara ni o, Olorun ara koseni to mo le fi owe.

WRITTEN BY
ADEOLA MARTINS


Comment on "ADEOLA MARTINS - Olorun Ara Lyrics "

  • LIKE GOSPEL MUSIC ON FACEBOOK :

This Week's Top Song

Top 200 Ugandan Gospel Songs Of All Time - Luganda Worship NonStop Mix by Dj Vin Vicent | GMP Mixes
Downlod Song Play Song

GMP Mixes-Top 200 Ugandan Gospel Songs Of All Time - Luganda Worship NonStop Mix by Dj Vin Vicent