"AYO" From GMP PROMOTIONS
Ayo Lyrics by Tope Alabi ft TY Bello
{Ayo to kun inu wa
Erin to gba enu wa kan
Agbara toun te wa siwaju
Ogo ye ile re }x2
Ti ko ba si iwo, Eni araye so lokun mole, talo le tu?
Ti ko ba si iwo, ota a teri wa mole ama rin kaka
Iwo naa ni, Agbara toun te wa si waju
Iyin ye ilere Ooo
Ogo ye eni toh san julo
Ogo ye eni toh dara julo
Ogo ye iwo to dawa laworan re to fayo kun inu wa
Ogo ye ilere
Ota ofe kayo Iwo lerin toh gba enu wa
Ota ofe kayo Bi ka te eba ka ma ri obe fi je ni
Iwo lagbara toun te wa siwaju, Daddy ogo ye ilere
Ayo to kun inu wa, Erin to gba enu wa kan
Agbara toun te wa siwaju, Ogo ye ile re
Ota boju wo wa oni taloun ba wa se bawo lase se
Iwo lerin toh kun enu wa, Iwo lagbara toun te wa siwaju
Baba oo, Ogo ye ilere
Won ti bere pe bawo la se sey gan (keyboardist play Ayo to kun inu wa erin to gba enu wa kan agbara toun te wa siwaju ogo ye ile re)
Igba mi ran wa tun sowipe soun nikan ni se oni ori meji
Sugbon okan je ayo wa si be oje erin wa sibe
Osi je agbara toun te wasiju
To ba se ni ti ota, Ero eyin loun fe je ka je
Ooo Ogo ye eni toh san julo, Ogo ye eni toh dara julo
Ogo ye iwo to dawa laworan re to fayo kun inu wa, Ogo ye ilere
Iwo ni ayo toh kun inu wa, Erin to gba enu wa kan
Agabara toun te wa siwaju, Ogo ye ile re
Thank you Lord Jesus.
WRITTEN BY
TOPE ALABI
This Week's Top Song
Abatukuvu |
Dr Mponye
Downlod Song
Play Song
Trending
RECENT SEARCHES (0)
VIEW ALLFeatured Song
Twalibaddewa |
Grace Nakimera
Downlod Song
Play Song
Comment on "Tope Alabi - Ayo Lyrics "